Sáàmù 59:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n èmi ó kọrin agbára Rẹ,ń ó kọrin ìfẹ́ Rẹ ní òwúrọ̀;nítorí ìwọ ni ààbò mi,ibi ìsádì mi ní ìgbà ìpọ́njú.

Sáàmù 59

Sáàmù 59:9-17