Sáàmù 49:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí àgùntàn ni a tẹ́ wọn sínú isà òkúikú yóò jẹun lórí wọn;ẹni tí ó dúró ṣinṣin ní yóòjọba lórí wọn ní òwúrọ̀;Ẹwà wọn yóò díbàjẹ́isà òkú ni ibùgbé ẹwà wọn.

Sáàmù 49

Sáàmù 49:12-20