Sáàmù 47:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọgẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run Ábúráhámùnítorí asà ayé ti Ọlọ́run niòun ni ó ga jùlọ.

Sáàmù 47

Sáàmù 47:5-9