Sáàmù 47:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run jọba lórí gbogbo ayé;Ọlọ́run jókòó lórí ìtẹ́ ìwà mímọ́ Rẹ̀

Sáàmù 47

Sáàmù 47:1-9