Sáàmù 46:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí omi Rẹ̀ tilẹ̀ ń hó tí ó sì ń mìtí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ń mì pẹ̀lú ọwọ́ agbára Rẹ̀. Sela

Sáàmù 46

Sáàmù 46:1-10