Sáàmù 45:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo aṣọ Rẹ̀ ni ó ń rùn pẹ̀lú òjíá àti alóe àti kaṣíà;láti inú ààfin tí a fi eyín erin ṣeorin olókùn tẹ́ẹ́rẹ́ mú inú Rẹ̀ dùn.

Sáàmù 45

Sáàmù 45:1-14