Sáàmù 45:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ fẹ́ olódodo, ìwọ sì kórìíra ìwà búburúnígbà náà Ọlọ́run, Ọlọ́run Rẹ̀ ti yàn ọ́ ṣe olórí àwọn ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀,nípa fífí àmì òróró ayọ̀ kùn ọ́

Sáàmù 45

Sáàmù 45:1-8