Sáàmù 44:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípaṣẹ̀ Rẹ̀ ni àwa ó bi àwọn ọ̀tá wa ṣúbú; nípasẹ̀ orúkọ Rẹ ni àwa ó tẹ àwọn ọ̀tá ti ó dìde sí wa mọ́lẹ̀

Sáàmù 44

Sáàmù 44:2-14