Sáàmù 44:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ni ọba àti Ọlọ́run mi,ẹni tí ó pàṣẹ ìṣẹ́gun fún Jákọ́bù.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:1-8