Sáàmù 44:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jí, Olúwa! Èéṣe tí ìwọ ń sùn?Dìde fún ra Rẹ! Má ṣe kọ̀ wá sílẹ̀ láéláé.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:20-24