Sáàmù 44:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n wọ́n kọ lù wá,ìwọ sì sọ wá di ẹran ọdẹ fún àwọn ajákotí wọn sì fi òkùnkùn biribiri bò wá mọ́lẹ̀.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:11-25