Sáàmù 44:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn wa kò padà sẹ́yìn;bẹ́ẹ̀ ni ẹsẹ̀ wa kò yẹ̀ kúrò ní ọ̀nà Rẹ̀.

Sáàmù 44

Sáàmù 44:9-22