Sáàmù 42:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òùngbẹ Ọlọ́run ń gbẹ ọkàn mi, fún Ọlọ́run alààyè.Nígbà wo ni èmi ó lọ bá Ọlọ́run?

Sáàmù 42

Sáàmù 42:1-5