Sáàmù 41:8-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. wọ́n wí pé “Ohun búburú ni ó di mọ́-ọn sinsinàti ní ibi tí ó dùbúlẹ̀ sí,kì yóò dìde mọ́”.

9. Pàápàá ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́, ẹni tí mo gbẹ́kẹ̀lé,ẹni tí ó ń jẹ nínú oúnjẹ mi,tí gbé gìgíṣẹ̀ Rẹ̀ sókè sí mi.

10. Ṣùgbọ́n ìwọ Olúwa, ṣàánú fún mi;gbé mi sókè, kí ń ba lè san fún wọn.

11. Èmi mọ̀ pé inú Rẹ̀ dùn sí mi,nítorí ọ̀tá mi kò borí mi.

12. Bí ó ṣe tèmi niìwọ dì mí mú nínú ìwà òtítọ́ miìwọ sì gbé mi kalẹ̀ níwájú Rẹ títí láé.

Sáàmù 41