Sáàmù 41:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pàápàá ọ̀rẹ́ mi tímọ́tímọ́, ẹni tí mo gbẹ́kẹ̀lé,ẹni tí ó ń jẹ nínú oúnjẹ mi,tí gbé gìgíṣẹ̀ Rẹ̀ sókè sí mi.

Sáàmù 41

Sáàmù 41:8-13