Sáàmù 41:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò gbà á lórí àkéte àìsàn Rẹ̀yóò sì mú-un padà bọ̀ sípò kúrò nínú àìsàn Rẹ̀.

Sáàmù 41

Sáàmù 41:1-4