Sáàmù 38:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Àwọn tí wọn ń fiibi san rere fún miàwọn ni ọ̀ta minítorí pé mò ń tọ ire lẹ́yìn.

21. Má ṣe kọ̀ mí sílẹ̀,ìwọ Olúwa!Ọlọ́run miMá ṣe jìnnà sí mi

22. Yára láti ràn mí lọ́wọ́, Olúwa,Olùgbàlà mi.

Sáàmù 38