Sáàmù 38:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. OlúwaMá ṣe bá mi wí nínú ìbínú Rẹ,bẹ́ẹ̀ ni kí o má ṣe fi ìyà jẹ mínínú ìrunú Rẹ̀.

2. Nítorí tí ọfà Rẹkàn mọ́ mi ṣinṣin,ọwọ́ Rẹ sìkì mí mọ́lẹ̀.

3. Kò sí ibi yíyè ní ara à minítorí ìbínú Rẹ;kò sí àlàáfíà nínú egungun minítorí i ẹ̀ṣẹ̀ mi.

4. Nítorí àìṣedédé miti borí mi mọ́lẹ̀;wọ́n tó ìwọ̀n bi àjàgàtí ó wúwo jù fún mi:

5. Ọgbẹ́ mi ń rùnó sì díbàjẹ́nítorí òmùgọ̀ mi;

Sáàmù 38