Sáàmù 36:11-12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Má ṣe jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ agbéragakí ó wá sí orí mi,kí ọwọ́ àwọn ènìyànbúburú sí mi ni ipò.

12. Níbẹ̀ ni àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀gbé subú sí:a Rẹ̀ wọ́n sílẹ̀,wọn kì yóò le è dìde!

Sáàmù 36