Sáàmù 37:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe ìkanra nítorí àwọnolùṣe búburú,kí ìwọ má sì ṣe ṣe ìlàra nítorí àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀;

Sáàmù 37

Sáàmù 37:1-6