Sáàmù 33:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kó àwọn omi òkun jọ gẹ́gẹ́ bí èyí tí ó wà nínú ìgò;ó sì fi ibú sí ilé ìṣúra gbogbo.

Sáàmù 33

Sáàmù 33:1-9