Sáàmù 33:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípaṣẹ̀ ọ̀rọ̀ Olúwa ni a ṣe dá àwọn ọ̀run,àti gbogbo àwọn ẹgbẹ́ ogun wọn nípa ìmísí ẹnu Rẹ̀.

Sáàmù 33

Sáàmù 33:1-15