Sáàmù 31:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣàánú fún mi, ìwọ Olúwa, nítorí mo wà nínú ìpọ́njú;ojú mi fi ìbìnújẹ́ sùn,ọkàn àti ara mi pẹ̀lú.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:4-15