Sáàmù 31:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi fi ìbànújẹ́ lo ọjọ́ miàti àwọn ọdún mi pẹ̀lú ìmí ẹ̀dùn;agbára mi ti kùnà nítorí òṣì mi,egungun mi sì ti rún dànù.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:7-14