Sáàmù 31:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùbùkún ni Olúwa,nítorí pé ó ti fi àgbà ìyanu ìfẹ́ tí ó ní sí mi hànnígbà tí mo wà ní ìlú tí wọ́n rọ̀gbà yí ká.

Sáàmù 31

Sáàmù 31:20-24