Sáàmù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá.Kí ìbùkún Rẹ̀ wà lóri àwọn ènìyàn Rẹ̀. Sela

Sáàmù 3

Sáàmù 3:7-8