Sáàmù 3:7-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

7. Dìde, Olúwa!Gbà mí, Ọlọ́run mi!Lu gbogbo àwọn ọ̀ta mi ní àgbọ̀n;kí o sì ká eyín àwọn ènìyàn búburú.

8. Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá.Kí ìbùkún Rẹ̀ wà lóri àwọn ènìyàn Rẹ̀. Sela

Sáàmù 3