Sáàmù 3:5-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Èmi dúbùú lẹ̀, mo sì sùn;mo sì tún padà jí, nítorí Olúwa ni ó ń gbé mi ró.

6. Èmi kì yóò bẹ̀rù ẹgbẹgbẹ̀rún ènìyàntí wọ́n rọ̀gbà yí mi ká.

7. Dìde, Olúwa!Gbà mí, Ọlọ́run mi!Lu gbogbo àwọn ọ̀ta mi ní àgbọ̀n;kí o sì ká eyín àwọn ènìyàn búburú.

8. Láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìgbàlà ti wá.Kí ìbùkún Rẹ̀ wà lóri àwọn ènìyàn Rẹ̀. Sela

Sáàmù 3