Sáàmù 23:5-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Ìwọ tẹ́ tábìlì oúnjẹ sílẹ̀ níwájú ù miní ojú àwọn ọ̀tá à mi;ìwọ ta òróró sí mi ní orí;ago mí sì kún àkún wọ́ sílẹ̀.

6. Nítòótọ, ire àti àánú ni yóò máa tọ̀ mí lẹ́yìnní ọjọ́ ayé è mi gbogbo,èmi yóò sì máa gbé inú ilé Olúwatítí láéláé.

Sáàmù 23