Sáàmù 23:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ tẹ́ tábìlì oúnjẹ sílẹ̀ níwájú ù miní ojú àwọn ọ̀tá à mi;ìwọ ta òróró sí mi ní orí;ago mí sì kún àkún wọ́ sílẹ̀.

Sáàmù 23

Sáàmù 23:3-6