Sáàmù 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lati ọ̀dọ̀ Rẹ̀ ni ẹsẹ̀ ìyìn mi nínú àwùjọ ńlá yóò ti wá;ẹ̀jẹ́ Rẹ̀ ni èmi yóò san níwájú àwọn tí o bẹ̀rù Rẹ̀

Sáàmù 22

Sáàmù 22:19-26