Sáàmù 21:9-11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Nígbà tí ìwọ bá yọìwọ yóò mú wọn dàbí ìnà ìléru. Olúwa yóò gbé wọn mì nínú ìbínú Rẹ̀,àti pé iná Rẹ̀ yóò jó wọn run.

10. Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀,àti irú ọmọ wọn kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.

11. Bí o tilẹ̀ jẹ́ wí pé wọ́n ro èrò ibi sí ọwọ́n sì ń pète ìwà-ìkà, wọn kì yóò ṣe àṣeyọrí.

Sáàmù 21