Sáàmù 21:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀,àti irú ọmọ wọn kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.

Sáàmù 21

Sáàmù 21:9-11