Sáàmù 21:10-13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

10. Ìwọ yóò pa ìrandíran wọn run kúrò lórí ilẹ̀,àti irú ọmọ wọn kúrò láàrin àwọn ọmọ ènìyàn.

11. Bí o tilẹ̀ jẹ́ wí pé wọ́n ro èrò ibi sí ọwọ́n sì ń pète ìwà-ìkà, wọn kì yóò ṣe àṣeyọrí.

12. Nítorí pé ìwọ yóò mú wọn yí ẹ̀yìn wọn padànígbà tí o bá pinnu láti ta wọ́n ní ọfà.

13. Gbígbéga ni ọ Olúwa, nínú agbára Rẹ;a ó kọrin, a ó yín agbára a Rẹ̀.

Sáàmù 21