Sáàmù 2:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èéṣe tí àwọn orílẹ̀ èdè fi ń dìtẹ̀,àti tí àwọn ènìyàn ń ṣe rìkísí asán?

2. Àwọn ọba ayé péjọ pọ̀àti àwọn ìjòyè gbìmọ̀ pọ̀sí Olúwaàti sí Ẹni àmì òróró Rẹ̀.

Sáàmù 2