Sáàmù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa, báwo ni àwọn ọ̀ta mi ṣe pọ̀ tó!Báwo ni àwọn ti ó dìde sí mi ṣe pọ̀ tó!

Sáàmù 3

Sáàmù 3:1-8