Sáàmù 18:48 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ó pa mí mọ́ kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mí.Ìwọ gbé mi ga ju àwọn tí ó dìde sí mi lọ;lọ́wọ́ àwọn ènìyàn alágbára ni ìwọ ti gbà mí.

Sáàmù 18

Sáàmù 18:42-50