Sáàmù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ní ojú ẹni tí ènìyàn-kénìyàn di gígànṣùgbọ́n ó bọ̀wọ̀ fún àwọn tí ó bẹ̀rù Olúwa,Ẹni tí ó búra sí ibi ara Rẹ̀àní tí kò sì yípadà,

Sáàmù 15

Sáàmù 15:1-5