Sáàmù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí kò fi ahọ́n Rẹ̀ sọ̀rọ̀ ẹni lẹ́yìn,tí kò ṣe ibi sí aládùúgbò Rẹ̀tí kò sì sọ̀rọ̀ ẹ̀gàn sí ẹnìkejì Rẹ̀,

Sáàmù 15

Sáàmù 15:1-5