Sáàmù 149:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí àwọn ènìyàn mímọ́ kí ó yọ̀ nínú ọlá Rẹ̀kí wọn kí ó máa kọrin fún ayọ̀ ní orí ibùsùn wọn.

Sáàmù 149

Sáàmù 149:4-9