Sáàmù 149:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Olúwa ní inú dídùn sí àwọn ènìyàn Rẹ̀ó fi ìgbàlà dé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé

Sáàmù 149

Sáàmù 149:1-9