Sáàmù 146:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa ń dá ààbò bo àwọn àlejòó sì ń dá àwọn aláìní baba àti opó síṣùgbọ́n ó ba ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú jẹ́.

Sáàmù 146

Sáàmù 146:3-10