Sáàmù 146:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa mú àwọn afọ́jú ríran Olúwa, gbé àwọn tí a Rẹ̀ sílẹ̀ ga Olúwa fẹ́ràn àwọn olódodo.

Sáàmù 146

Sáàmù 146:4-10