Sáàmù 146:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe ní ìgbẹkẹ̀lé nínú àwọn ọmọ aládé,àní, ọmọ ènìyàn,lọ́wọ́ ẹni tí kò sí ìrànlọ́wọ́.

Sáàmù 146

Sáàmù 146:1-4