Sáàmù 146:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò yin Olúwa ní gbogbo ayé mièmi yóò kọrin ìyìn sí Ọlọ́run,níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè.

Sáàmù 146

Sáàmù 146:1-6