Sáàmù 137:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ẹ̀bá odò Bábílónì, níbẹ̀ ní àwa gbé jókòóàwa sì sunkún nígbà tí àwa rántí Síónì.

2. Àwa fi dùùrù wa kọ́ sí orí igi wílóò,tí ó wà láàrin Rẹ̀.

Sáàmù 137