Sáàmù 13:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà;ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà Rẹ.

Sáàmù 13

Sáàmù 13:1-6