Sáàmù 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀tá mi wí pé, “Èmi ti ṣẹ́gun Rẹ̀,”àwọn ọ̀ta mi yóò yọ̀ tí mo bá ṣubú.

Sáàmù 13

Sáàmù 13:1-6