1. Bí kò ṣè pé Olúwa bá kọ́ ile náààwọn tí n kọ ọ ńṣiṣẹ́ lásán ni;bí kò sé pé Olúwa bá pa ilú mọ́, olùṣọ́ jí lásán.
2. Asán ni fún ẹ̀yin ti ẹ dìde ní kùtùkùtùlati pẹ́ dùbúlẹ̀, láti jẹ oúnjẹ́ làálàá;bẹ́ẹ̀ ni ó ń fi ire fún olùfẹ́ Rẹ̀ lójú ọ̀run.
3. Kíyèsí i, àwọn ọmọ ni ìní Olúwa:ọmọ inú sì ni èrè Rẹ̀.
4. Bí ọfà ti rí ní ọwọ́ alágbára,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ èwe