Sáàmù 124:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. “Ìba má ṣe pé Olúwa tí ó ti wà fún wa”ni kí Ísírẹ́lì kí ó máa wí nísinsìn yìí;

2. “Ìbá má ṣe pé Olúwa tó wà ní tiwa,”Nígbà tí àwọn ènìyàn dúró sí wa:

3. Nígbà náà ni wọn ò bá gbé wà mì láàyènígbà tí ìbínú wọn ru sí wá

4. Nígbà náà ni omiwọ̀n-ọn-nì ìbá bò wá mọ́lẹ̀

5. Nígbà náà ni agbéragaomi ìbá borí ọkàn wa.

Sáàmù 124